ISO 639-1
Ìrísí
ISO 639-1:2002, Àwọn àmì ọ̀rọ̀ fún ìṣojú àwọn orúkọ àwọn èdè Àdàkọ:-- Apá 1: àmì ọ̀rọ̀ Alpha-2 ní apá kinní ISO 639 àwon eseese [[International Organization for Standardization|opagun káríayé] fún àwon àmì òrò èdè. Apá kinní dá lórí ìforúkosílè àwon àmì òrò létà méjì. Àwon àmì òrò létà méjì mérìndínlógóòje(136) ni wón jé fíforúkosílè. Àwon àmì òrò tí wón jé fíforúkosílè jé ti gbogbo àwon èdè àgbáyé koko.
Àwon àmì òrò wònyí jé wíwúlò káríayé láti se ìgékúúrú èdè. Fún àpeere:
- Yorùbá jé sísojù pèlú yo
- Geesi jé sísojù pèlú en
- Igbo jé sísojù pèlú ig
- Èdè Germany jé sísojù pèlú de (láti endonym Deutsch)
- Japanese jé sísojú pèlú ja (bí ó tilè jé pé endonym rè ni Nihongo)
- Èdè Swahili jé sísojù pèlú kw (lati endonym Kiswahili)
- Portuguese jé sísojù pèlú pt
- Spanish jé sísojù pèlú es (láti endonym Español)[1][2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "ISO 639-2 Language Code List". Codes for the representation of names of languages (Library of Congress) (in Lùṣẹ́mbọ́ọ̀gì). Retrieved 2019-09-30.
- ↑ "Language Codes ISO 639-1". MathGuide. Archived from the original on 2019-10-03. Retrieved 2019-09-30.